40 years as ago was the earliest birthday I knew when Dad celebrated my 10th birthday (with Toyin). It was great but how I longed and wished Mum was physically there, but I wasn’t privileged to see my Mum witness my 10th birthday for she’d passed away few months earlier.
‘Aye
t’esin o je, iru idi’e t’o ba mu suuru a je ni irinwo’
This is more
of my celebration as hers, as she clocks 10. My mother become my daughter has
been granted the mercy of having her mother and father intact. We do not take
that for granted.
‘Eni t’o
ni iya (ati baba) ko mo’yi , eni ti’o ni ni ki e bi! Oluwa a da wa si fun awon
omo wa o. Olorun Alaaye a da awon omo wa so fun wa o’
‘A dupe
fun gbogbo eyin ebi ti e se oju-seeyin, e seun a mo o l’oore o.
Iro ope
ni a o ma a gbo ni agbala olododo. Nkan aayo ni a’a ma ba ara wa se o.
‘Aridunu
ni Oluwa fi se won fun wa, won o ni di ari sokun o’
Mercy is 10!
The Lord has
truly been gracious and merciful!
Ti Oluwa ni
gbogbo ogo!
No comments:
Post a Comment